Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 30:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Hesekiah, ọba Juda, ta ijọ enia na li ọrẹ, ẹgbẹrun akọ-malu, ati ẹ̃dẹgbãrun àgutan: ọ̀pọlọpọ ninu awọn alufa si yà ara wọn si mimọ́.

Ka pipe ipin 2. Kro 30

Wo 2. Kro 30:24 ni o tọ