Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 28:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Woli Oluwa kan si wà nibẹ, orukọ ẹniti ijẹ Odedi: o si jade lọ ipade ogun ti o wá si Samaria, o si wi fun wọn pe, Kiyesi i, nitoriti Oluwa Ọlọrun awọn baba nyin binu si Juda li on ṣe fi wọn le nyin lọwọ, ẹnyin si pa wọn ni ipa-oro ti o de òke ọrun.

Ka pipe ipin 2. Kro 28

Wo 2. Kro 28:9 ni o tọ