Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 28:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahasi si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, nwọn si sìn i ni ilu na, ani ni Jerusalemu; ṣugbọn nwọn kò mu u wá sinu awọn isa-okú awọn ọba Israeli: Hesekiah ọmọ rẹ si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Kro 28

Wo 2. Kro 28:27 ni o tọ