Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 28:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ti o rubọ si awọn oriṣa Damasku, awọn ẹniti o kọlù u: o si wipe, Nitoriti awọn oriṣa awọn ọba Siria ràn wọn lọwọ, nitorina li emi o rubọ si wọn, ki nwọn le ràn mi lọwọ. Ṣugbọn awọn na ni iparun rẹ̀ ati ti gbogbo Israeli.

Ka pipe ipin 2. Kro 28

Wo 2. Kro 28:23 ni o tọ