Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 28:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ara Filistia pẹlu ti gbé ogun lọ si ilu pẹtẹlẹ wọnni, ati siha gusu Juda, nwọn si ti gbà Bet-ṣemeṣi, ati Ajaloni, ati Gederoti, ati Ṣoko pẹlu ileto rẹ̀, Timna pẹlu ileto rẹ̀, ati Gimso pẹlu ati ileto rẹ̀: nwọn si ngbe ibẹ.

Ka pipe ipin 2. Kro 28

Wo 2. Kro 28:18 ni o tọ