Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 24:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹmi Ọlọrun si bà le Sakariah, ọmọ Jehoiada alufa, ti o duro ni ibi giga jù awọn enia lọ, o si wi fun wọn pe, Bayi li Ọlọrun wi pe, Ẽṣe ti ẹnyin fi ru ofin Oluwa, ẹnyin kì yio ri ire? nitoriti ẹnyin ti kọ̀ Oluwa silẹ, on pẹlu si ti kọ̀ nyin.

Ka pipe ipin 2. Kro 24

Wo 2. Kro 24:20 ni o tọ