Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 23:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li awọn ọmọ Lefi ati gbogbo Juda ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti Jehoiada, alufa ti pa á ni aṣẹ, olukuluku si mu awọn enia rẹ̀ ti o nwọle li ọjọ isimi, pẹlu awọn ti o njade li ọjọ isimi nitori Jehoiada alufa, kò jọwọ awọn ẹgbẹ meji alufa lọwọ lọ.

Ka pipe ipin 2. Kro 23

Wo 2. Kro 23:8 ni o tọ