Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 23:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo ijọ enia si ba ọba dá majẹmu ni ile Ọlọrun. O si wi fun wọn pe, Kiyesi i, ọmọ ọba ni yio jọba, gẹgẹ bi Oluwa ti wi niti awọn ọmọ Dafidi.

Ka pipe ipin 2. Kro 23

Wo 2. Kro 23:3 ni o tọ