Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 23:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu awọn olori-ọrọrun, ati awọn ọlọla, ati awọn bãlẹ ninu awọn enia ati gbogbo enia ilẹ na, nwọn si mu ọba sọ̀kalẹ lati ile Oluwa wá: nwọn si gbà ẹnu-ọ̀na giga wá sinu ile ọba, nwọn si gbé ọba ka ori itẹ ijọba na.

Ka pipe ipin 2. Kro 23

Wo 2. Kro 23:20 ni o tọ