Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 23:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tò gbogbo awọn enia tì ọba kakiri olukuluku pẹlu ohun ijà rẹ̀ li ọwọ rẹ̀, lati apa ọtún ile na titi de apa òsi ile na, lẹba pẹpẹ ati lẹba ile na.

Ka pipe ipin 2. Kro 23

Wo 2. Kro 23:10 ni o tọ