ATI li ọdun keje, Jehoiada mu ọkàn le, o si ba awọn olori ọrọrún dá majẹmu pẹlu, ani Asariah, ọmọ Jerohamu ati Iṣmaeli, ọmọ Jehohanani, ati Asariah ọmọ Obedi, ati Maaseiah, ọmọ Adaiah, ati Eliṣafati ọmọ Sikri.