Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 20:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehoṣafati si jọba lori Juda: o si wà li ẹni ọdun marundilogoji, nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, o si jọba ọdun mẹdọgbọn ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ si ni Asuba, ọmọbinrin Ṣilhi.

Ka pipe ipin 2. Kro 20

Wo 2. Kro 20:31 ni o tọ