Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 20:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin kò ni ijà li ọ̀ran yi; ẹ tẹgun, ẹ duro jẹ, ki ẹ si ri igbala Oluwa lọdọ nyin, iwọ Juda ati Jerusalemu: ẹ máṣe bẹ̀ru, bẹ̃ni ki ẹ má si ṣe fòya: lọla, ẹ jade tọ̀ wọn: Oluwa yio si pẹlu nyin.

Ka pipe ipin 2. Kro 20

Wo 2. Kro 20:17 ni o tọ