Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 18:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Israeli si wi fun Jehoṣafati pe, emi o pa aṣọ dà, emi o si lọ si oju ìja; ṣugbọn iwọ gbé aṣọ igunwà rẹ wọ̀. Bẹ̃li ọba Israeli si pa aṣọ dà: nwọn si lọ si oju ìja.

Ka pipe ipin 2. Kro 18

Wo 2. Kro 18:29 ni o tọ