Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 15:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si jade lọ ipade Asa, o si wi fun u pe, Ẹ gbọ́ temi, Asa, ati gbogbo Juda ati Benjamini! Oluwa pẹlu nyin, nitori ti ẹnyin ti wà pẹlu rẹ̀; bi ẹnyin ba si ṣafẹri rẹ̀, ẹnyin o ri i; ṣugbọn bi ẹnyin ba kọ̀ ọ, on o si kọ̀ nyin.

Ka pipe ipin 2. Kro 15

Wo 2. Kro 15:2 ni o tọ