Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 13:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia lasan si ko ara wọn jọ si ọdọ rẹ̀, awọn ọmọ ẹni buburu, nwọn si mu ara wọn le si Rehoboamu, ọmọ Solomoni, nigbati Rehoboamu wà li ọdọmọde ti inu rẹ̀ si rọ̀, ti kò si le kò wọn loju.

Ka pipe ipin 2. Kro 13

Wo 2. Kro 13:7 ni o tọ