Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 12:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Oluwa ri pe nwọn rẹ̀ ara wọn silẹ, ọ̀rọ Oluwa tọ̀ Ṣemaiah wá, wipe, Nwọn ti rẹ̀ ara wọn silẹ; nitorina emi kì o run wọn, ṣugbọn emi o fun wọn ni igbala diẹ: a kì yio dà ibinu mi sori Jerusalemu nipa ọwọ Ṣiṣaki.

Ka pipe ipin 2. Kro 12

Wo 2. Kro 12:7 ni o tọ