Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 12:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ iṣe Rehoboamu, ti iṣaju ati ti ikẹhin, a kò ha kọ wọn sinu iwe Ṣemaiah, woli, ati ti Iddo, ariran, nipa iwe itan idile? Ọtẹ si wà lãrin Rehoboamu ati Jeroboamu nigbagbogbo.

Ka pipe ipin 2. Kro 12

Wo 2. Kro 12:15 ni o tọ