Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 10:18-19 Yorùbá Bibeli (YCE)

18. Nigbana ni Rehoboamu ọba ran Hadoramu ti iṣe olori iṣẹ-irú; awọn ọmọ Israeli si sọ ọ li okuta, o si kú. Ṣugbọn Rehoboamu ọba yara lati gun kẹkẹ́ rẹ̀ lati salọ si Jerusalemu.

19. Bẹ̃ni Israeli si ya kuro lọdọ ile Dafidi titi o fi di oni yi.

Ka pipe ipin 2. Kro 10