Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina a fi ọgbọ́n on ìmọ fun ọ, Emi o si fun ọ ni ọrọ̀, ọlá, tabi ọlà, iru eyiti ọba kan ninu awọn ti nwọn wà ṣaju rẹ kò ni ri, bẹ̃ni lẹhin rẹ kì yio si ẹniti yio ni iru rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Kro 1

Wo 2. Kro 1:12 ni o tọ