Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. A. Ọba 11:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Jehoṣeba ọmọbinrin Joramu ọba, arabinrin Ahasiah, mu Joaṣi ọmọ Ahasiah, o si ji i gbé kuro ninu awọn ọmọ ọba ti a pa; nwọn si pa a mọ́ ninu iyẹ̀wu kuro lọdọ Ataliah, on, ati alagbatọ́ rẹ̀, ti a kò si fi pa a.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 11

Wo 2. A. Ọba 11:2 ni o tọ