Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 9:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si dide ni kutukutu: o si ṣe, li afẹmọjumọ, Samueli si pe Saulu sori orule, wipe, Dide, emi o si ran ọ lọ. Saulu si dide, awọn mejeji sì jade, on ati Samueli, si gbangba.

Ka pipe ipin 1. Sam 9

Wo 1. Sam 9:26 ni o tọ