Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 8:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Eyi ni yio ṣe ìwa ọba na ti yio jẹ lori nyin: yio mu awọn ọmọkunrin nyin, yio si yàn wọn fun ara rẹ̀ fun awọn kẹkẹ́ rẹ̀, ati fun ẹlẹṣin rẹ̀, nwọn o si ma sare niwaju kẹkẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 8

Wo 1. Sam 8:11 ni o tọ