Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 7:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AWỌN ọkunrin Kirjatjearimu wá, nwọn gbe apoti Oluwa na, nwọn si mu u wá si ile Abinadabu ti o wà lori oke, nwọn si ya Eleasari ọmọ rẹ̀ si mimọ́ lati ma tọju apoti Oluwa.

Ka pipe ipin 1. Sam 7

Wo 1. Sam 7:1 ni o tọ