Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 6:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ ṣe kẹkẹ titun kan nisisiyi, ki ẹ si mu abo malu meji ti o nfi ọmu fun ọmọ, eyi ti kò ti igbà ajaga si ọrun ri, ki ẹ si so o mọ kẹkẹ́ na, ki ẹnyin ki o si mu ọmọ wọn kuro lọdọ wọn wá ile.

Ka pipe ipin 1. Sam 6

Wo 1. Sam 6:7 ni o tọ