Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 6:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wipe, Bi ẹnyin ba rán apoti Ọlọrun Israeli lọ, máṣe rán a lọ lofo; ṣugbọn bi o ti wu ki o ri, ẹ ṣe irubọ ẹbi fun u; a o si mu nyin lara da, ẹnyin o si mọ̀ ohun ti o ṣe ti ọwọ́ rẹ̀ kò fi kuro li ara nyin.

Ka pipe ipin 1. Sam 6

Wo 1. Sam 6:3 ni o tọ