Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 6:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹliri wura na si ri gẹgẹ bi iye gbogbo ilu awọn Filistini ti o jasi ti awọn ijoye marun na, ati ilu, ati ilu olodi, ati awọn ileto, titi o fi de ibi okuta nla Abeli, lori eyi ti nwọn gbe apoti Oluwa kà: okuta eyiti o wà titi di oni ninu oko Joṣua ara Betṣemeṣi.

Ka pipe ipin 1. Sam 6

Wo 1. Sam 6:18 ni o tọ