Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 6:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kẹkẹ́ na si wọ inu oko Joṣua, ara Betṣemeṣi, o si duro nibẹ, ibi ti okuta nla kan gbe wà: nwọn la igi kẹkẹ na, nwọn si fi malu wọnni ru ẹbọ sisun si Oluwa.

Ka pipe ipin 1. Sam 6

Wo 1. Sam 6:14 ni o tọ