Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 6:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn abo malu na si lọ tàra si ọ̀na Betṣemeṣi, nwọn si nke bi nwọn ti nlọ li ọ̀na opopo, nwọn kò yà si ọtún tabi si osì; awọn ijoye Filistini tẹle wọn lọ si agbegbe Betṣemeṣi.

Ka pipe ipin 1. Sam 6

Wo 1. Sam 6:12 ni o tọ