Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 5:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni nwọn ranṣẹ, nwọn si pe gbogbo ijoye Filistini jọ, nwọn si wipe, Rán apoti Ọlọrun Israeli lọ, ki ẹ si jẹ ki o tun pada lọ si ipò rẹ̀, ki o má ba pa wa, ati awọn enia wa: nitoriti ipaiya ikú ti wà ni gbogbo ilu na; ọwọ́ Ọlọrun si wuwo gidigidi ni ibẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 5

Wo 1. Sam 5:11 ni o tọ