Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 4:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia si de budo, awọn agbà Israeli si wipe, Nitori kini Oluwa ṣe le wa loni niwaju awọn Filistini? Ẹ jẹ ki a mu apoti majẹmu Oluwa ti mbẹ ni Ṣilo sọdọ wa, pe, nigbati o ba de arin wa, ki o le gba wa kuro lọwọ awọn ọta wa.

Ka pipe ipin 1. Sam 4

Wo 1. Sam 4:3 ni o tọ