Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 31:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn ọkunrin Israeli ti o wà li apa keji afonifoji na, ati awọn ẹniti o wà li apa keji Jordani, ri pe awọn ọkunrin Israeli sa, ati pe Saulu ati awọn ọmọbibi rẹ̀ si kú, nwọn si fi ilu silẹ, nwọn si sa; awọn Filistini si wá, nwọn si joko si ilu wọn.

Ka pipe ipin 1. Sam 31

Wo 1. Sam 31:7 ni o tọ