Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 29:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣe eyi ni Dafidi ti nwọn tori rẹ̀ gberin ara wọn ninu ijo wipe, Saulu pa ẹgbẹgbẹrun rẹ̀, Dafidi si pa ẹgbẹgbãrun tirẹ̀?

Ka pipe ipin 1. Sam 29

Wo 1. Sam 29:5 ni o tọ