Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 28:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Obinrin na si tọ Saulu wá, o si ri i pe o wà ninu ibanujẹ pupọ, o si wi fun u pe, Wõ, iranṣẹbinrin rẹ ti gbọ́ ohùn rẹ, emi si ti fi ẹmi mi si ọwọ́ mi, emi si ti gbọ́ ọ̀rọ ti iwọ sọ fun mi.

Ka pipe ipin 1. Sam 28

Wo 1. Sam 28:21 ni o tọ