Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 27:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wi fun Akiṣi pe, Bi o ba jẹ pe emi ri ore ọfẹ loju rẹ, jẹ ki wọn ki o fun mi ni ibi kan ninu awọn ileto wọnni; emi o ma gbe ibẹ: ẽṣe ti iranṣẹ rẹ yio si ma ba ọ gbe ni ilu ọba?

Ka pipe ipin 1. Sam 27

Wo 1. Sam 27:5 ni o tọ