Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 26:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wi fun Abneri pe, Alagbara ọkunrin ki iwọ nṣe ndan? tali o si dabi iwọ ni Israeli? njẹ ẽṣe ti iwọ ko tọju ọba oluwa rẹ? nitori ẹnikan ninu awọn enia na ti wọle wá lati pa ọba oluwa rẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 26

Wo 1. Sam 26:15 ni o tọ