Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 25:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ mo gbọ́ pe, awọn olùrẹrun mbẹ lọdọ rẹ; Wõ, awọn oluṣọ agutan rẹ ti wà lọdọ wa, awa kò ṣe wọn ni iwọsi kan, bẹ̃ni ohun kan ko si nù lọwọ wọn, ni gbogbo ọjọ ti nwọn wà ni Karmeli.

Ka pipe ipin 1. Sam 25

Wo 1. Sam 25:7 ni o tọ