Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 25:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si gbọ́ pe Nabali kú, o si wi pe, Iyin ni fun Oluwa ti o gbeja gigàn mi lati ọwọ́ Nabali wá, ti o si da iranṣẹ rẹ̀ duro lati ṣe ibi: Oluwa si yi ikà Nabali si ori on tikalarẹ̀. Dafidi si ranṣẹ, o si ba Abigaili sọ̀rọ lati mu u fi ṣe aya fun ara rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 25

Wo 1. Sam 25:39 ni o tọ