Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 25:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi ki yio si jasi ibinujẹ fun ọ, tabi ibinujẹ ọkàn fun oluwa mi, nitoripe iwọ ta ẹjẹ alaiṣẹ silẹ, tabi pe oluwa mi gbẹsan fun ara rẹ̀: ṣugbọn nigbati Oluwa ba ṣe ore fun oluwa mi, njẹ ranti iranṣẹbinrin rẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 25

Wo 1. Sam 25:31 ni o tọ