Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 25:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Orukọ ọkunrin na si njẹ Nabali, orukọ aya rẹ̀ si njẹ Abigaili; on si jẹ oloye obinrin, ati arẹwa enia; ṣugbọn onroro ati oniwa buburu ni ọkunrin; ẹni idile Kalebu li on si ṣe.

Ka pipe ipin 1. Sam 25

Wo 1. Sam 25:3 ni o tọ