Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 25:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ, oluwa mi, bi Oluwa ti wà lãye, ati bi ẹmi rẹ si ti wà làye, bi Oluwa si ti da ọ duro lati wá ta ẹjẹ silẹ, ati lati fi ọwọ́ ara rẹ gbẹsan; njẹ, ki awọn ọta rẹ, ati awọn ẹniti ngbero ibi si oluwa mi ri bi Nabali.

Ka pipe ipin 1. Sam 25

Wo 1. Sam 25:26 ni o tọ