Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 25:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wi fun awọn ọmọkunrin rẹ̀ pe, Ki olukuluku nyin ki o di idà rẹ̀ mọ idi. Olukuluku ọkunrin si di idà rẹ̀ mọ idi; ati Dafidi pẹlu si di idà tirẹ̀: iwọn irinwo ọmọkunrin si goke tọ Dafidi lẹhin; igba si joko nibi ẹrù.

Ka pipe ipin 1. Sam 25

Wo 1. Sam 25:13 ni o tọ