Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 24:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọkunrin Dafidi si wi fun u pe, Wõ, eyi li ọjọ na ti Oluwa wi fun ọ pe, Wõ, emi o fi ọta rẹ le ọ li ọwọ́, iwọ o si ṣe si i gẹgẹ bi o ti tọ li oju rẹ. Dafidi si dide, o si yọ lọ ike eti aṣọ Saulu.

Ka pipe ipin 1. Sam 24

Wo 1. Sam 24:4 ni o tọ