Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 24:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wõ, oju rẹ ri loni, bi Oluwa ti fi iwọ le mi li ọwọ́ loni ni iho nì: awọn kan ni ki emi ki o pa ọ: ṣugbọn emi dá ọ si; emi si wipe, emi ki yio nawọ́ mi si oluwa mi, nitoripe ẹni-ami-ororo Oluwa li on iṣe.

Ka pipe ipin 1. Sam 24

Wo 1. Sam 24:10 ni o tọ