Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 23:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ si lọ si Keila, nwọn si ba awọn ara Filistia jà, nwọn si ko ohun ọsìn wọn, nwọn si fi iparun nla pa wọn. Dafidi si gbà awọn ara Keila silẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 23

Wo 1. Sam 23:5 ni o tọ