Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 23:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si bere lọdọ Oluwa pe, Ki emi ki o lọ kọlu awọn ara Filistia wọnyi bi? Oluwa si wi fun Dafidi pe. Lọ, ki o si kọlu awọn ara Filistia ki o si gbà Keila silẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 23

Wo 1. Sam 23:2 ni o tọ