Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 23:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn agba ilu Keila yio fi mi le e lọwọ bi? Saulu yio ha sọkalẹ, gẹgẹ bi iranṣẹ rẹ ti gbọ́ bi? Oluwa Ọlọrun Israeli, emi bẹ̀ ọ, wi fun iranṣẹ rẹ. Oluwa si wipe, Yio sọkalẹ wá.

Ka pipe ipin 1. Sam 23

Wo 1. Sam 23:11 ni o tọ