Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 22:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti gbogbo nyin fi dimọlù si mi, ti kò fi si ẹnikan ti o sọ ọ li eti mi pe, ọmọ mi ti ba ọmọ Jesse mulẹ, bẹ̃ni kò si si ẹnikan ninu nyin ti o ṣanu mi, ti o si sọ ọ li eti mi pe, ọmọ mi mu ki iranṣẹ mi dide si mi lati ba dè mi, bi o ti ri loni?

Ka pipe ipin 1. Sam 22

Wo 1. Sam 22:8 ni o tọ