Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 22:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olukuluku ẹniti o ti wà ninu ipọnju, ati olukuluku ẹniti o ti jẹ gbesè, ati olukuluku ẹniti o wà ninu ibanujẹ, si ko ara wọn jọ sọdọ rẹ̀, on si jẹ olori wọn: awọn ti o wà lọdọ rẹ̀ si to iwọn irinwo ọmọkunrin.

Ka pipe ipin 1. Sam 22

Wo 1. Sam 22:2 ni o tọ