Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 22:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si wi fun Doegi pe, Iwọ, yipada, ki o si pa awọn alufa. Doegi ara Edomu si yipada, o si kọlu awọn alufa, o si pa li ọjọ na, àrunlelọgọrin enia ti nwọ aṣọ ọgbọ̀ Efodu.

Ka pipe ipin 1. Sam 22

Wo 1. Sam 22:18 ni o tọ